Pular para o conteúdo
Publicidade

Efesu 6:1-3

Àwọn ọmọ àti àwọn òbí

1 Ẹ̀yin ọmọ, ẹ máa gbọ́ tí àwọn òbí i yín nínú Olúwa, nítorí pé èyí ní ó tọ́. 2 6.2: Ek 20.12."Bọ̀wọ̀ fún baba àti ìyá rẹ," èyí tí í ṣe òfin kìn-ín-ní pẹ̀lú ìlérí, 3 6.3: De 5.16."ki ó lé dára fún ọ, àti kí ìwọ lè wà pẹ́ ní ayé."

Estes versículos te tocaram? Ore agora!

+581 estão orando agora.

Junte-se à corrente de oração.