33 Nígbà tí Jesu rí i, tí ó ń sọkún, àti àwọn Júù tí ó bá a wá ń sọkún pẹ̀lú rẹ̀, ó kérora nínú ẹ̀mí, inú rẹ̀ sì bàjẹ́.
35 11.35: Lk 19.41. Jesu sọkún.
Jesu jí òkú Lasaru dìde
38 11.38: Mt 27.60; Mk 15.46; Lk 24.2; Jh 20.1. Nígbà náà ni Jesu tún kérora nínú ara rẹ̀, ó wá sí ibojì, ó sì jẹ́ ihò, a sì gbé òkúta lé ẹnu rẹ̀.