Pular para o conteúdo
Publicidade

Johanu 13:6-8

6 Nígbà náà ni ó dé ọ̀dọ̀ Simoni Peteru, òun sì wí fún un pé, "Olúwa, ìwọ yóò ha wẹ ẹsẹ̀ mi?"

7 Jesu dá a lóhùn, ó sì wí fún un pé, "Ohun tí èmi ń ṣe ni ìwọ kò mọ̀ nísinsin yìí; ṣùgbọ́n yóò yé ọ ní ìkẹyìn."

8 13.8: De 12.12; Jh 3.5; 9.7. Peteru wí fún un pé, "Ìwọ kì yóò wẹ̀ ẹsẹ̀ mi láé."

Jesu sì dalóhùn pé, "Bí èmi kò bá wẹ̀ ọ́, ìwọ kò ní ìpín ní ọ̀dọ̀ mi."

Estes versículos te tocaram? Ore agora!

+581 estão orando agora.

Junte-se à corrente de oração.