Pular para o conteúdo
Publicidade

Johanu 9:1-3

Jesu la ojú ẹni tí a bí ní afọ́jú

1 Bí ó sì ti ń kọjá lọ, ó rí ọkùnrin kan tí ó fọ́jú láti ìgbà ìbí rẹ̀ wá. 2 9.2: Lk 13.2; Ap 28.4; El 18.20; El 20.5.Àwọn ọmọ-ẹ̀yìn rẹ̀ sì bi í léèrè, pé, "Rabbi, ta ní ó dẹ́ṣẹ̀, ọkùnrin yìí tàbí àwọn òbí rẹ̀, tí a fi bí i ní afọ́jú?"

3 9.3: Jh 11.4. Jesu dáhùn pé, "Kì í ṣe nítorí pé ọkùnrin yìí dẹ́ṣẹ̀, tàbí àwọn òbí rẹ̀: ṣùgbọ́n kí a ba à lè fi iṣẹ́ Ọlọ́run hàn lára rẹ̀.

Estes versículos te tocaram? Ore agora!

+581 estão orando agora.

Junte-se à corrente de oração.