5 9.5: Jh 1.4; 8.12; 12.46.Níwọ́n ìgbà tí mo wà láààyè, èmi ni ìmọ́lẹ̀ ayé."
6 9.6: Mk 7.33; 8.23. Nígbà tí ó ti wí bẹ́ẹ̀ tan, ó tutọ́ sílẹ̀, ó sì fi itọ́ náà ṣe amọ̀, ó sì fi amọ̀ náà ra ojú afọ́jú náà. 7 9.7: Lk 13.4.Ó sì wí fún un pé, "Lọ wẹ̀ nínú adágún Siloamu!" (Ìtumọ̀ ọ̀rọ̀ yìí ni "rán"). Nítorí náà ó gba ọ̀nà rẹ̀ lọ, ó wẹ̀, ó sì dé, ó ń ríran.
39 9.39: Jh 5.27; 3.19; Mt 15.14. Jesu sì wí pé, "Nítorí ìdájọ́ ni mo ṣe wá sí ayé yìí, kí àwọn tí kò ríran lè ríran; àti kí àwọn tí ó ríran lè di afọ́jú."