Oúnjẹ alẹ́ Olúwa
12 14.12-16: Mt 26.17-19; Lk 22.7-13. Ní ọjọ́ kìn-ín-ní àjọ̀dún ìrékọjá tí í ṣe ọjọ́ tí wọ́n máa ń pa ẹran àgùntàn fún ìrúbọ, àwọn ọmọ-ẹ̀yìn Jesu bi í léèrè pé, "Níbo ni ìwọ fẹ́ kí a lọ pèsè sílẹ̀ tí ìwọ yóò ti jẹ àsè ìrékọjá?"
26 14.26-31: Mt 26.30-35; Lk 22.33-34,39. Lẹ́yìn náà wọ́n kọ orin, wọ́n sì gun orí òkè olifi lọ.
Ọgbà Getsemane
32 14.32-42: Mt 26.36-46; Lk 22.40-46; Hb 5.7-8. Nígbà tí wọ́n dé ibi kan tí wọ́n ń pè ní ọgbà Getsemane. Jesu wí fún àwọn ọmọ-ẹ̀yìn rẹ̀ pé, "Ẹ jókòó dè mí níhìn-ín títí n ó fi lọ gbàdúrà."
A mú Jesu
43 14.43-50: Mt 26.47-56; Lk 22.47-53; Jh 18.2-11. Bí ó sì ti ń sọ̀rọ̀ lọ́wọ́, lójú ẹsẹ̀ náà ni Judasi ọ̀kan nínú àwọn ọmọ-ẹ̀yìn méjìlá dé pẹ̀lú. Ọ̀pọ̀lọpọ̀ ènìyàn ti idà àti kùmọ̀ lọ́wọ́, àwọn olórí àlùfáà, àwọn olùkọ́ òfin àti àwọn àgbàgbà Júù ni ó rán wọn wá.
46 Wọ́n sì mú Jesu.