Pular para o conteúdo
Publicidade

Marku 14:61,62

61 Ṣùgbọ́n Jesu dákẹ́.

Olórí àlùfáà tún bi í, lẹ́ẹ̀kan sí i, ó ní, "Ṣé ìwọ ni Kristi náà, Ọmọ Olùbùkún un nì?"

62 14.62: Da 7.13; Mk 9.1; 13.26. Jesu wá dáhùn, ó ni, "Èmi ni, ẹ̀yin yóò sì rí Ọmọ Ènìyàn tí yóò jókòó lọ́wọ́ ọ̀tún agbára. Ẹ̀yin yóò sì tún rí Ọmọ Ènìyàn tí ó ń bọ̀ láti inú àwọsánmọ̀ ojú ọ̀run."

Estes versículos te tocaram? Ore agora!

+581 estão orando agora.

Junte-se à corrente de oração.