Pular para o conteúdo
Publicidade

Matiu 14

Jesu rìn lójú omi

22 14.22-23: Mk 6.45-46; Jh 6.15-17. Lẹ́sẹ̀kẹsẹ̀ lẹ́yìn èyí, Jesu fún àwọn ọmọ-ẹ̀yìn rẹ̀ wọ́n bọ sínú ọkọ̀ wọn, àti wọ́n máa kọjá lọ ṣáájú rẹ̀ òdìkejì. Òun náà dúró lẹ́yìn láti àwọn ènìyàn lọ ilé wọn. 23 Lẹ́yìn ó ìjọ ènìyàn tán, ó gun orí òkè lọ fúnra rẹ̀ láti lọ gba àdúrà. Nígbà ilẹ̀ ṣú, òun nìkan níbẹ̀, 24 14.24-33: Mk 6.47-52; Jh 6.16-21.àkókò yìí ọkọ̀ ojú omi náà ti rin jìnnà etí bèbè Òkun, ìjì omi ń í síwá sẹ́yìn, nítorí ìjì ṣe ọwọ́ òdì wọn.

25 déédé ago mẹ́rin òwúrọ̀, Jesu tọ̀ wọ́n , ó ń rìn lórí omi. 26 14.26: Lk 24.37.Nígbà àwọn ọmọ-ẹ̀yìn i ó ń rìn lójú omi, ̀ba wọn gidigidi, wọ́n "iwin ni," wọ́n kígbe tìbẹ̀tìbẹ̀.

27 Lójúkan náà, Jesu fún wọn , "ọkàn le! Èmi ni ṣe bẹ̀."

28 Peteru i , "Olúwa, ó jẹ́ ìwọ ni nítòótọ́, sọ n tọ̀ ́ lórí omi."

29 14.29: Jh 21.7. Jesu a lóhùn , "Ó dára, máa bọ̀ ."

Nígbà náà ni Peteru sọ̀kalẹ̀ láti inú ọkọ̀. Ó ń rìn lórí omi lọ ìhà ̀dọ̀ Jesu. 30 Nígbà ó afẹ́fẹ́ líle, ̀á, ó bẹ̀rẹ̀ í . Ó kígbe lóhùn rara , "Gbà , Olúwa."

31 14.31: Mt 6.30; 8.26; 16.8. Lójúkan náà, Jesu na ọwọ́ rẹ̀, ó dìímú, ó gbà á. Ó fún un , "Èéṣe ìwọ fi ṣiyèméjì ìwọ onígbàgbọ́ kékeré?"

32 Àti , nígbà ti wọ́n gòkè sínú ọkọ̀, ìjì náà dúró jẹ́́. 33 14.33: Mt 28.9,17.Nígbà náà ni àwọn to nínú ọkọ̀ náà foríbalẹ̀ fún un wọ́n , "Nítòótọ́ Ọmọ Ọlọ́run ni ìwọ í ṣe."

Veja também