Pular para o conteúdo
Publicidade

Matiu 5:3-10

3 5.3: Mk 10.14; Lk 22.29. "Alábùkún fún ni àwọn òtòṣì ní ẹ̀mí,

nítorí tiwọn ni ìjọba ọ̀run.

4 5.4: Isa 61.2; Jh 16.20; If 7.17. Alábùkún fún ni àwọn tí ń ṣọ̀fọ̀,

nítorí a ó tù wọ́n nínú.

5 5.5: Sm 37.11. Alábùkún fún ni àwọn ọlọ́kàn tútù,

nítorí wọn yóò jogún ayé.

6 5.6: Isa 55.1-2; Jh 4.14; 6.48-51. Alábùkún fún ni àwọn tí ebi ń pa

tí òǹgbẹ ń gbẹ́ nítorí òdodo, nítorí wọn yóò yó.

7 Alábùkún fún ni àwọn aláàánú,

nítorí wọn yóò rí àánú gbà.

8 5.8: Sm 24.4; Hb 12.14; 1Jh 3.2; If 22.4. Alábùkún fún ni àwọn ọlọ́kàn mímọ́,

nítorí wọn yóò rí Ọlọ́run.

9 Alábùkún fún ni àwọn onílàjà,

nítorí ọmọ Ọlọ́run ni a ó máa pè wọ́n.

10 5.10: 1Pt 3.14; 4.14. Alábùkún fún ni àwọn ẹni tí a ṣe inúnibíni sí,

nítorí tí wọ́n jẹ́ olódodo

nítorí tiwọn ní ìjọba ọ̀run.

Estes versículos te tocaram? Ore agora!

+581 estão orando agora.

Junte-se à corrente de oração.