Pular para o conteúdo
Publicidade

Romu 10:8,9

8 10.8: De 30.14.Ṣùgbọ́n kí ni ó wí? "Ọ̀rọ̀ náà wà létí ọ̀dọ̀ rẹ̀, ní ẹnu rẹ̀, àti ní ọkàn rẹ̀," èyí nì ni ọ̀rọ̀ ìgbàgbọ́, tí àwa ń wàásù pé: 9 10.9: Mt 10.32; Lk 12.8; Ap 16.31.Bí ìwọ bá fi ẹnu rẹ̀ jẹ́wọ́ "Jesu ní Olúwa," tí ìwọ si gbàgbọ́ ní ọkàn rẹ pé, Ọlọ́run jí i dìde kúrò nínú òku, a ó gbà ọ́ là.

Estes versículos te tocaram? Ore agora!

+581 estão orando agora.

Junte-se à corrente de oração.