Pular para o conteúdo
Publicidade

Romu 5:8,9

8 5.8: Jh 15.13; Ro 8.32; 1Pt 3.18; 1Jh 3.16; 4.10.Ṣùgbọ́n Ọlọ́run fi ìfẹ́ òun pàápàá sí wa hàn nínú èyí pé, nígbà tí àwa jẹ́ ẹlẹ́ṣẹ̀, Kristi kú fún wa.

9 5.9: Ro 3.5,24-25; Ef 1.7; 1Tẹ 1.10. Mélòó mélòó sì ni tí a dá wa láre nísinsin yìí nípa ẹ̀jẹ̀ rẹ̀ ni a ó gbà wá là kúrò nínú ìbínú nípasẹ̀ rẹ̀.

Estes versículos te tocaram? Ore agora!

+581 estão orando agora.

Junte-se à corrente de oração.