Pular para o conteúdo
Publicidade

1 Kọrinti 12

12 12.12: Ro 12.4. Ara jẹ́ ̀kan ó àwọn ̀púpọ̀, ṣùgbọ́n gbogbo àwọn ̀ara ó pọ̀ wọ̀nyí ni ó papọ̀ láti jẹ́ ara kan ṣoṣo. Bákan náà ni ó pẹ̀ara Kristi í ṣe ìjọ. 13 12.13: Ga 3.28; Kl 3.11; Ef 2.13-18; Jh 7.37-39.Nítorí nínú ̀kan a ti bamitiisi gbogbo wa sínú ara kan, ìbá à ṣe Júù, ìbá à ṣe Giriki, ìbá à ṣe ẹrú, ìbá à ṣe òmìnira, gbogbo wa ni a mu nínú ̀Mímọ́ kan náà. 14 Bẹ́̀ ni, ara, í ṣe ̀kan ṣoṣo ṣe púpọ̀.

15 ẹsẹ̀ , "Nítorí èmi í ṣe ọwọ́, èmi í ṣe ti ara," èyí í ṣe ̀kan lára nínú ̀ara. 16 etí , "Nítorí èmi í ṣe ojú, èmi í ṣe apá kan ara," èyí le ó jẹ́ apá kan ara mọ́. 17 gbogbo ara jẹ́ ojú, níbo ni ìgbọ́ran ìbá gbé ? gbogbo ara jẹ́ etí, níbo ni ìgbóórùn ìbá gbé ? 18 Ṣùgbọ́n Ọlọ́run ti fi àwọn ̀ara si ara wa, ó fi ̀kọ̀̀kan ibi ó fẹ́ ó . 19 gbogbo wọn jẹ́ ̀kan ṣoṣo nínú ̀ara, níbo ni ara yóò gbé . 20 Ọlọ́run ̀ara púpọ̀, ṣùgbọ́n ara kan ṣoṣo ni.

21 ó yìí, ojú sọ fún ọwọ́ , "Èmi nílò rẹ." Bẹ́̀ ni orí le sọ fún ẹsẹ̀ , "Èmi nílò rẹ." 22 Àwọn ̀ara ó dàbí ẹni wọ́n ṣe aláìlágbára jùlọ, ó dàbí ẹni ṣe pàtàkì rárá, àwọn gan an ni a le ṣe aláìnílò. 23 Bẹ́̀ ni ̀ara a lọ́rárá ni àwa ń fi ọlá fún jùlọ. Àwọn ̀ara a ko yẹ rárá ni àwa ń fi si ipò ọlá ̀yẹ ó ga jùlọ. 24 Nítorí àwọn ibi ó ̀yẹ ara wa nílò ìtọ́̀tọ̀. Ṣùgbọ́n Ọlọ́run ti pa gbogbo ̀ara pọ̀ ṣọ̀kan lọ́kan, ó ti fi ̀yẹ ga jùlọ fún ibi ó ṣe aláìní. 25 ó ṣe ìyàtọ̀ nínú ara, ṣùgbọ́n àwọn ̀ara le máa jẹ́ olùrànlọ́wọ́ fún ara wọn. 26 ̀ara kan ń jìyà, gbogbo àwọn ̀ara ìyókù a máa a pín nínú ìyà náà. a bu ọlá fún ̀ara kan, gbogbo ̀ara ìyókù a máa a yọ̀.

27 12.27: Ef 1.23; 4.12; Kl 1.18,24; Ef 5.30; Ro 12.5. Gbogbo yín jẹ́ ara Kristi, ẹnìkọ̀̀kan yín jẹ́ ̀ara ̀tọ̀̀tọ̀ nínú ara Kristi.

Veja também