Pular para o conteúdo
Publicidade

1 Kọrinti 2:9,10

9 2.9: Isa 64.4; 65.17.Gẹ́gẹ́ bí a ti kọ ọ́ pé:

"Ojú kò tí ì rí,

etí kò tí í gbọ́,

kò sì ọkàn ènìyàn tí ó tí í mọ̀

ohun tí Ọlọ́run tí pèsè sílẹ̀ fún àwọn tí o fẹ́ ẹ."

10 2.10: Mt 11.25; 13.11; 16.17; Ef 3.3,5. Ṣùgbọ́n Ọlọ́run ti fi í hàn fún wa nípasẹ̀ Ẹ̀mí rẹ̀.

Ẹ̀mí á máa wádìí ohun gbogbo, kódà àwọn àṣírí Ọlọ́run tó jinlẹ̀ jùlọ.

Estes versículos te tocaram? Ore agora!

+581 estão orando agora.

Junte-se à corrente de oração.