Pular para o conteúdo
Publicidade

1 Kọrinti 5:12,13

12 5.12: Mk 4.11. Nítorí èwo ni tèmi láti máa ṣe ìdájọ́ àwọn tí ń bẹ lóde? Kì í ha ṣe àwọn tí ó wà nínú ni ẹ̀yin ṣe ìdájọ́ wọn? 13 5.13: De 17.7; 1Kọ 5.2.Ọlọ́run yóò ṣe ìdájọ́ àwọn tí ó ń bẹ lóde. "Ẹ lé àwọn ènìyàn búburú náà kúrò láàrín yín."

Estes versículos te tocaram? Ore agora!

+581 estão orando agora.

Junte-se à corrente de oração.