Pular para o conteúdo
Publicidade

1 Kọrinti 6:12,13

Ìwà àgbèrè

12 6.12: 1Kọ 10.23. "Ohun gbogbo ní ó tọ́ fún mi," ṣùgbọ́n kì í ṣe ohun gbogbo ni ó ní èrè. "Ohun gbogbo ni ó yẹ fún mi," ṣùgbọ́n èmi kì yóò jẹ́ kí ohunkóhun ṣe olórí fun mi. 13 "Oúnjẹ fún inú àti inú fún oúnjẹ," ṣùgbọ́n Ọlọ́run yóò fi òpin sí méjèèjì, ara kì í ṣe fún ìwà àgbèrè ṣíṣe, ṣùgbọ́n fún Olúwa, àti Olúwa fún ara náà.

Estes versículos te tocaram? Ore agora!

+581 estão orando agora.

Junte-se à corrente de oração.