Pular para o conteúdo
Publicidade

2 Pedro 2

Àwọn olùkọ́ni èké àti ìparun wọn

1 2.1-18: Jd 4-16. Ṣùgbọ́n àwọn wòlíì èké láàrín àwọn ènìyàn náà pẹ̀, gẹ́gẹ́ àwọn olùkọ́ni èké yóò ti láàrín yín. Wọn yóò yọ́ kẹ́lẹ́ ̀kọ́ òdì àti ègbé tọ̀ yín wa, àní yóò sẹ́ Olúwa ó wọ́n padà, wọ́n ó ìparun ti o yára kánkán sórí ara wọn. 2 ̀pọ̀lọpọ̀ ni yóò si máa tẹ̀̀ìtìjú wọn, wọn yóò ̀òtítọ́ di ìsọ̀rọ̀-òdì . 3 Nínú ìwà wọ̀bìà wọn, àwọn ẹlẹ́kọ̀́ òdì wọ̀nyí yóò máa rẹ́ yín jẹ nípa ìtàn asán. Ìdájọ́ ẹni falẹ̀ láti ìgbà yìí àti ìparun wọn tòògbé.

Veja também

2 Pedro
Ver todos os capítulos de 2 Pedro