Publicidade

Daniel 7

Ìdájọ́ níwájú ẹni ìgbàanì

9 7.9: If 1.14; 20.4,11. "mo ṣe ń ,

"a gbé ìtẹ́ ọba kan kalẹ̀,

ẹni ìgbàanì jókòó sórí ìtẹ́ rẹ̀.

Aṣọ rẹ̀ funfun ̀gbọ̀n òwú;

irun orí rẹ̀ funfun òwú,

ìtẹ́ ọba rẹ̀ ọwọ́ iná.

Àwọn kẹ̀kẹ́ rẹ ń i iná.

10 7.10: If 5.11; 20.12. Odò iná ń sàn,

ó ń jáde iwájú rẹ̀ .

Àwọn ẹgbẹ̀rún lọ́ẹgbẹ̀rún ń ṣe ìránṣẹ́ fún un;

̀ẹgbẹẹgbàárùn-ún nígbà ẹgbàárùn-ún dúró níwájú rẹ̀.

Àwọn onídàájọ́ jókòó,

a ṣí ìwé wọ̀n-ọn-nì sílẹ̀.

Veja também

Bíblia Online Bíblia Online

Bíblia Online • Versão: 2026-07-05_12-11-46-