Pular para o conteúdo
Publicidade

Heberu 10

Ìrúbọ Kristi lẹ́̀kan ṣoṣo fún gbogbo ènìyàn

1 Nítorí òfin jẹ́ òjìji àwọn ohun rere ti ń bọ̀ í ṣe àwòrán tòótọ́ fún àwọn òtítọ́ náà, wọn fi ẹbọ kan náà wọn ń nígbà gbogbo lọ́dọọdún mu àwọn ń jọ́sìn di pípé. 2 ṣe bẹ́̀, a ìbá dẹ́kun àti máa wọn, nítorí àwọn ti ń sìn ki ìbá ìmọ̀ ̀ṣẹ̀, nígbà a ti wẹ̀ wọ́n mọ́ lẹ́̀kan ṣoṣo. 3 Ṣùgbọ́n nínú ẹbọ wọ̀nyí ni a ń ṣe ìrántí ̀ṣẹ̀ lọ́dọọdún. 4 Nítorí ko ṣe é ṣe fún ̀jẹ̀ akọ màlúù àti ti ewúrẹ́ láti ̀ṣẹ̀ kúrò.

Estes versículos te tocaram? Ore agora!

+581 estão orando agora.

Junte-se à corrente de oração.

Veja também