Pular para o conteúdo
Publicidade

Heberu 12

5 12.5-8: Òw 3.11-12.̀yin ti gbàgbé ̀rọ̀ ìyànjú ó n ba yin sọ̀rọ̀ ọmọ ,

"Ọmọ mi, ma ṣe aláìnání ìbáwí Olúwa,

o ṣe rẹ̀wẹ̀nígbà a ń ti ọwọ́ rẹ̀ ba ,

6 nítorí ẹni ti Olúwa fẹ́, òun ni i ,

a máa na olúkúlùkù ọmọ òun tẹ́wọ́gbà."

7 máa sùúrù lábẹ́ ìbáwí, Ọlọ́run wa ọmọ ni; nítorí ọmọ wo ni ń bẹ ti baba í ? 8 Ṣùgbọ́n ̀yin ba láìsí ìbáwí, nínú èyí gbogbo ènìyàn ti jẹ alábápín, ǹjẹ́ ọmọ àlè ni yín, í ṣe ọmọ. 9 Pẹ̀lúpẹ̀àwa ni baba wa nípa ti ara o ń tọ́ wa, àwa ń bu ọlá fún wọn: ha yẹ a kúkú tẹríba fún Baba àwọn ̀, a ? 10 Nítorí wọ́n tọ́ wa fún ọjọ́ díẹ̀ o ti dára lójú wọn; ṣùgbọ́n Òun tọ́ wa fún èrè wa, àwa ṣe alábápín ìwà mímọ́ rẹ̀. 11 Gbogbo ìbáwí dàbí ohun ayọ̀ nísinsin yìí ṣe ìbànújẹ́; ṣùgbọ́n níkẹyìn yóò so èso àlàáfíà fún àwọn a tọ́ nípa rẹ̀, àní èso òdodo.

Veja também