Pular para o conteúdo
Publicidade

Heberu 13:1-3

Ìparí àwọn ọ̀rọ̀ ìyànjú náà

1 Kí ìfẹ́ ará kí o wà títí. 2 13.2: Gẹ 18.1-8; 19.1-3.Ẹ má ṣe gbàgbé láti máa ṣe àlejò; nítorí pé nípa bẹ́ẹ̀ ni àwọn ẹlòmíràn ṣe àwọn angẹli ní àlejò láìmọ̀. 3 Ẹ máa rántí àwọn òǹdè bí ẹni tí a dè pẹ̀lú wọn, àti àwọn tí a ń pọn lójú bí ẹ̀yin tìkára yín pẹ̀lú tí ń bẹ nínú ara.

Estes versículos te tocaram? Ore agora!

+581 estão orando agora.

Junte-se à corrente de oração.