Pular para o conteúdo
Publicidade

Heberu 3:7,8,12,13,15

Ìkìlọ̀ fún aláìgbàgbọ́

7 3.7-11: Sm 95.7-11. Nítorí náà gẹ́gẹ́ bi Ẹ̀mí Mímọ́ tí wí:

"Lónìí bí ẹ̀yin bá gbọ́ ohùn rẹ̀,

8 ẹ má ṣe sé ọkàn yín le,

bí ìgbà ìṣọ̀tẹ̀,

bí i ní ọjọ́ ìdánwò ní aginjù,

12 Ẹ kíyèsára, ará, kí ọkàn búburú ti àìgbàgbọ́ má ṣe wà nínú ẹnikẹ́ni yín, ní lílọ kúrò lọ́dọ̀ Ọlọ́run alààyè. 13 Ṣùgbọ́n ẹ máa gba ara yín ní ìyànjú ní ojoojúmọ́, níwọ̀n ìgbà tí a bá ń pè ní "Òní," kí a má ba à sé ọkàn ẹnikẹ́ni nínú yín le nípa ẹ̀tàn ẹ̀ṣẹ̀. 15 3.15: Sm 95.7-8.Nígbà tí a ń wí pé,

"Lónìí bí ẹ̀yin bá gbọ́ ohùn rẹ̀,

ẹ má sé ọkàn yin le,

bí ìgbà ìṣọ̀tẹ̀."

Estes versículos te tocaram? Ore agora!

+581 estão orando agora.

Junte-se à corrente de oração.