Pular para o conteúdo
Publicidade

João 6

Jesu bọ́ ẹgbẹ̀rún márùn-ún (5,000) ènìyàn

1 6.1-13: Mt 14.13-21; Mk 6.32-44; Lk 9.10-17. Lẹ́yìn nǹkan wọ̀nyí, Jesu kọjá apá kejì Òkun Galili, í ṣe Òkun Tiberia. 2 ̀pọ̀ ìjọ ènìyàn tọ̀ ́ lẹ́yìn, nítorí wọ́n iṣẹ́ àmì rẹ̀ ó ń ṣe lára àwọn aláìsàn. 3 Jesu gun orí òkè lọ, níbẹ̀ ni ó gbé jókòó pẹ̀àwọn ọmọ-ẹ̀yìn rẹ̀. 4 Àjọ ìrékọjá ọdún àwọn Júù súnmọ́ etílé.

5 6.5: Jh 1.43; 12.21. Ǹjẹ́ Jesu ti gbé ojú rẹ̀ sókè, ó ̀pọ̀ ènìyàn sọ́dọ̀ rẹ̀, ó fún Filipi , "Níbo ni a ó ti ra àkàrà, àwọn wọ̀nyí jẹ?" 6 Ó sọ èyí láti dán an ; nítorí òun fúnra rẹ̀ mọ ohun òun ó ṣe.

7 Filipi a lóhùn , "Àkàrà igba owó idẹ fún wọn, olúkúlùkù wọn tilẹ̀ í ju díẹ̀ jẹ."

8 6.8: Jh 1.40; 12.22. ̀kan nínú àwọn ọmọ-ẹ̀yìn rẹ̀, Anderu, arákùnrin Simoni Peteru fún un , 9 6.9: Jh 21.9-13."Ọmọdékùnrin kan ń bẹ níhìn-ín yìí, ó ìṣù àkàrà barle márùn-ún àti ẹja wẹ́wẹ́ méjì, ṣùgbọ́n kín ni ìwọ̀nyí jẹ́ láàrín ̀pọ̀ ènìyàn wọ̀nyí?"

10 Jesu , "àwọn ènìyàn náà jókòó!" Koríko púpọ̀ níbẹ̀. Bẹ́̀ ni àwọn ọkùnrin náà jókòó; ìwọ̀n ẹgbẹ̀rún márùn-ún (5,000) ènìyàn iye. 11 Jesu ìṣù àkàrà náà. Nígbà ó ti dúpẹ́, ó pín wọn fún àwọn ọmọ-ẹ̀yìn rẹ̀, àwọn ọmọ-ẹ̀yìn rẹ̀ pín wọn fún àwọn ó jókòó; bẹ́̀ gẹ́gẹ́ ni ẹja ìwọ̀n wọ́n ti ń fẹ́.

12 Nígbà wọ́n , ó fún àwọn ọmọ-ẹ̀yìn rẹ̀ , "àjẹkù ó jọ, ohunkóhun ṣe ṣòfò." 13 Bẹ́̀ ni wọ́n wọn jọ wọ́n fi àjẹkù ìṣù àkàrà barle márùn-ún náà kún agbọ̀n méjìlá, èyí àwọn ó jẹun jẹ .

14 6.14: Mt 21.11. Nítorí náà nígbà àwọn ọkùnrin náà iṣẹ́ àmì Jesu ṣe, wọ́n , "Lóòótọ́ èyí ni wòlíì náà ń bọ̀ ayé."

Veja também