Jesu ń kọ́ ẹ̀kọ́ nípa àdúrà
1 11.1: Mk 1.35; Lk 3.21; 5.16; 6.12; 9.18,28; 5.33; 7.18. Bí ó ti ń gbàdúrà ní ibi kan, bí ó ti dákẹ́, ọ̀kan nínú àwọn ọmọ-ẹ̀yìn rẹ̀ wí fún un pé, "Olúwa, kọ́ wa bí a ti ń gbàdúrà, bí Johanu ti kọ́ àwọn ọmọ-ẹ̀yìn rẹ̀."

+581 estão orando agora.
Junte-se à corrente de oração.