Pular para o conteúdo
Publicidade

Luku 23:39-43

39 Àti ọ̀kan nínú àwọn arúfin tí a gbé kọ́ ń fi ṣe ẹlẹ́yà wí pé, "Bí ìwọ bá ṣe Kristi, gba ara rẹ àti àwa náà là."

40 Ṣùgbọ́n èyí èkejì dáhùn, ó ń bá a wí pé, "Ìwọ kò bẹ̀rù Ọlọ́run, tí ìwọ wà nínú ẹ̀bi kan náà? 41 23.41: Lk 23.4,14,22.Ní tiwa, wọ́n jàre nítorí èrè ohun tí àwa ṣe ni à ń jẹ, ṣùgbọ́n ọkùnrin yìí kò ṣe ohun búburú kan."

42 Ó sì wí pé, "Jesu, rántí mi nígbà tí ìwọ bá dé ìjọba rẹ."

43 23.43: 2Kọ 12.3; If 2.7. Jesu sì wí fún un pé, "Lóòótọ́ ni mo wí fún ọ, lónìí ni ìwọ ó wà pẹ̀lú mi ní Paradise!"

Estes versículos te tocaram? Ore agora!

+581 estão orando agora.

Junte-se à corrente de oração.