Ìpè Lefi
27 5.27-32: Mt 9.9-13; Mk 2.13-17. Lẹ́hìn èyí, Jesu jáde lọ, ó sì rí agbowó òde kan tí à ń pè ní Lefi, ó jókòó sí ibi tí ó ti ń gba owó òde, Jesu sì wí fún un pé, "Tẹ̀lé mi," 28 Lefi sì fi ohun gbogbo sílẹ̀ ó sì ń tẹ̀lé e.

+581 estão orando agora.
Junte-se à corrente de oração.