Pular para o conteúdo
Publicidade

Mateus 13

Òwe ti àwọ̀n ẹja

47 13.47-50: Mt 13.40-42. "Bákan náà, a tún fi ìjọba ̀run àwọ̀n kan a sínú odò, ó onírúurú ẹja. 48 Nígbà àwọ̀n náà kún, àwọn apẹja á sókè etí bèbè Òkun, wọ́n jókòó, wọ́n ṣa àwọn èyí ó dára sínú apẹ̀rẹ̀, ṣùgbọ́n wọ́n da àwọn dára . 49 Bẹ́̀ gẹ́gẹ́ ni yóò ìgbẹ̀yìn ayé. Àwọn angẹli yóò láti ya àwọn ènìyàn búburú kúrò lára àwọn olódodo. 50 Wọn ó ju àwọn ènìyàn búburú sínú iná ìléru náà, ibi ti ẹkún àti ìpayínkeke yóò gbé ."

Veja também