Pular para o conteúdo
Publicidade

Matiu 7

3 7.3-5: Lk 6.41-42. "Èétiṣe ìwọ fi ń wo ̀rún igi ń bẹ ojú arákùnrin rẹ, ṣùgbọ́n ìwọ kíyèsi ìtì igi ń bẹ ojú ara rẹ? 4 Tàbí ìwọ ó ti ṣe fún arákùnrin rẹ , Jẹ́ èmi yọ ̀rún igi ń bẹ ni ojú rẹ,ó ìtì igi ń bẹ ojú ìwọ tìkára rẹ. 5 Ìwọ àgàbàgebè, tètè kọ́ yọ ìtì igi jáde kúrò ojú ara rẹ , nígbà náà ni ìwọ yóò ríran kedere láti yọ ̀rún igi ń bẹ ojú arákùnrin rẹ kúrò.

Veja também