Publicidade

Tito 2

3 Bákan náà, ni ó kọ́ àwọn àgbà obìnrin lẹ́kọ̀́ láti kọ́ à a gbé ìgbé ayé ẹni ̀wọ̀, wọn gbọdọ̀ jẹ́ afọ̀rọ̀kẹ́lẹ́ batẹnijẹ́ tàbí olùfẹ́ ọtí mímu, ṣùgbọ́n wọ́n gbọdọ̀ jẹ́ olùkọ́ni ohun rere. 4 Nípa èyí, wọ́n yóò máa kọ́ àwọn ̀dọ́bìnrin láti nífẹ̀́ àwọn ọkọ wọn àti àwọn ọmọ wọn, 5 láti jẹ́ ẹni ìwọ̀ntúnwọ̀nsì àti ọlọ́kàn mímọ́, wọ́n máa ṣe ojúṣe wọn nínú ilé, wọ́n gbọdọ̀ jẹ́ onínúrere, wọ́n máa tẹríba fún àwọn ọkọ wọ́n, ẹnikẹ́ni máa ba à sọ̀rọ̀-òdì ̀rọ̀ Ọlọ́run.

Veja também

Tito
Ver todos os capítulos de Tito
Bíblia Online Bíblia Online

Bíblia Online • Versão: 2026-07-05_19-25-13-