Pular para o conteúdo
Publicidade

2 Coríntios 1

Ọlọ́run gbogbo ìtùnú

3 1.3: Ef 1.3; 1Pt 1.3; Ro 15.5. Olùbùkún ni Ọlọ́run, àti Baba Jesu Kristi Olúwa wa, Baba ìyọ́, àti Ọlọ́run ìtùnú gbogbo. 4 1.4: 2Kọ 7.6-7,13.Ẹni ń nínú ni gbogbo ìdààmú wa, ki àwa pẹ̀máa tu àwọn ó nínú ìdààmú nínú, nípá ìtùnú náà ti a fi ń àwa fúnra wa nínú láti ̀dọ̀ Ọlọ́run . 5 Nítorí àwa ti pín nínú ìjìyà Kristi, gẹ́gẹ́ bẹ́̀ ìtùnú wa púpọ̀ pẹ̀nípa Kristi. 6 Ṣùgbọ́n a ń pọ́n wa lójú, ó jẹ́ fún ìtùnú àti ìgbàlà yín; tàbí bi a ń nínú, ó jẹ́ fún ìtùnú yín ti ń ṣiṣẹ́ sùúrù láti yin irú ìfaradà ìyà kan náà ti àwa pẹ̀ń jẹ́. 7 Àti ìrètí wa nípa tiyín dúró ṣinṣin, àwa si mọ̀ , ̀yin ti jẹ alábápín nínú ìyà wa, bẹ́̀ ni ̀yin ń pín nínú ìtùnú náà pẹ̀.

Veja também