Pular para o conteúdo
Publicidade

Daniel 6

Daniẹli nínú ihò kìnnìún

1 Ó dára lójú Dariusi láti yan ọgọ́àwọn baálẹ̀ sórí ìjọba, 2 pẹ̀alákòóso mẹ́ta, Daniẹli jẹ́ ̀kan nínú wọn, àwọn baálẹ̀ máa jẹ́ ààbọ̀ fún wọn, ọba ba à ìpalára. 3 Daniẹli ya ara rẹ̀ sọ́tọ̀ láàrín àwọn alákòóso àti àwọn baálẹ̀ nítorí ̀ó tayọ lára rẹ̀ bi ọba ń gbèrò láti fi ṣe olórí i gbogbo ìjọba. 4 Nítorí èyí, gbogbo àwọn alákòóso àti àwọn baálẹ̀ ń gbèrò láti ̀ṣẹ̀ Daniẹli lọ́rùn nínú ètò ìṣèjọba rẹ̀, ṣùgbọ́n wọn ̀ṣẹ̀ kankan i lọ́rùn, wọn ìwà ìbàjẹ́ kankan ó ṣe, nítorí ó jẹ́ olóòtítọ́ ìwà ìjáfara. 5 Nígbẹ̀yìn ni àwọn ọkùnrin wọ̀nyí sọ , "Àwa ìdí kankan láti ̀ṣẹ̀ Daniẹli lọ́rùn, àfi èyí ó í ṣe pẹ̀òfin Ọlọ́run rẹ̀."

6 Nígbà náà ni àwọn alákòóso àti àwọn baálẹ̀ lọ gẹ́gẹ́ ikọ̀ ̀dọ̀ ọba, wọ́n , "Ìwọ Dariusi ọba, o pẹ́! 7 Àwọn alákòóso ọba, ìjòyè, baálẹ̀, olùdámọ̀ràn, àti àwọn olórí gbìmọ̀ pọ̀ ọba kéde òfin kan ẹnikẹ́ni ó gba àdúrà Ọlọ́run tàbí ènìyàn kankan fún ọgbọ̀n ọjọ́, yàtọ̀ fún ìwọ ọba, a ó ju ẹni náà inú ihò kìnnìún. 8 Nísinsin yìí, ìwọ ọba, gbé òfin yìí jáde, o kọ ́ sínú ìwé a ba à i padà ìbámu pẹ̀òfin àwọn Media àti Persia, èyí le è parẹ́." 9 Nígbà náà, ni Dariusi ọba fi ọwọ́ ìwé àṣẹ náà.

10 Lóòótọ́, Daniẹli mọ̀ a ti fi ọwọ́ ìwé òfin náà, síbẹ̀ ó wọ ilé e rẹ̀ lọ, nínú yàrá òkè, ó ṣí fèrèsé èyí ó kọjú Jerusalẹmu sílẹ̀. Ó kúnlẹ̀ lórí orúnkún un rẹ̀ ̀̀mẹ́ta lójoojúmọ́, ó gbàdúrà, ó fi ọpẹ́ fún Ọlọ́run gẹ́gẹ́ ìṣe rẹ̀ tẹ́lẹ̀. 11 Nígbà náà ni, àwọn ọlọ̀tẹ̀ yìí ara wọn jọ, wọ́n Daniẹli ó ń gba àdúrà, ó ń bẹ̀bẹ̀ fún àánú lọ́dọ̀ Ọlọ́run. 12 Wọ́n lọ iwájú ọba, wọ́n rán ọba létí nípa òfin ó ṣe , "Ìwọ ha fi ọwọ́ òfin ìwọ̀n ọgbọ̀n ọjọ́ ẹnikẹ́ni ó gba àdúrà Ọlọ́run tàbí ènìyàn, láì ṣe ìwọ ọba, a ó gbé e sínú ihò kìnnìún?"

Ọba dáhùn , "Àṣẹ náà dúró síbẹ̀, ìbámu pẹ̀òfin àwọn ará Media àti Persia, èyí a le è parẹ́."

13 Nígbà náà, ni wọ́n sọ fún ọba , "Daniẹli, ̀kan lára ìgbèkùn Juda, ka ìwọ ọba , tàbí àṣẹ ̀ rẹ o fi ọwọ́ . Òun tún ń gba àdúrà ̀̀mẹ́ta lójúmọ́." 14 Nígbà ọba gbọ́ èyí, inú rẹ̀ bàjẹ́ gidigidi; ó pinnu láti Daniẹli yọ, títí oòrùn fi rọ̀, ó sa gbogbo ipá a rẹ̀ láti gba Daniẹli sílẹ̀.

15 Nígbà náà, ni àwọn ọlọ̀tẹ̀ wọ̀nyí ara wọn jọ ̀dọ̀ ọba, wọ́n fún un , "Ìwọ ọba rántí , ìbámu pẹ̀òfin àwọn Media àti Persia àṣẹ tàbí ìkéde ọba ṣe a le è i padà."

16 Nígbà náà, ni ọba pàṣẹ, wọ́n Daniẹli, wọ́n sọ ́ sínú ihò kìnnìún. Ọba sọ fún Daniẹli , "Ọlọ́run rẹ ìwọ ń sìn nígbà gbogbo ó gbà ́!"

17 A gbé òkúta kan , wọ́n fi ẹnu ihò náà, ọba í pa pẹ̀òrùka èdìdì rẹ̀ àti pẹ̀òrùka àwọn ọlọ́rẹ̀, nítorí a ṣe ohunkóhun padà nítorí i Daniẹli. 18 Nígbà náà ni ọba padà ààfin rẹ̀, ó lo gbogbo òru náà láì jẹun, gbọ́ orin kankan, bẹ́̀ ni le è sùn òru ọjọ́ náà.

19 òwúrọ̀ kùtùkùtù, ni ọba dìde ó sáré lọ ibi ihò kìnnìún náà. 20 Nígbà ó súnmọ́ ibi ihò náà ibi Daniẹli , ó pe Daniẹli pẹ̀ìtara , "Daniẹli, ìránṣẹ́ Ọlọ́run alààyè, ṣé Ọlọ́run rẹ ìwọ ń sìn tọ̀sán tòru, gbà ́ lọ́wọ́ kìnnìún ?"

21 Daniẹli dáhùn , "Ọba pẹ́! 22 Ọlọ́run mi rán angẹli i rẹ̀, ó àwọn kìnnìún lẹ́nu. Wọn le è pa lára, nítorí a mi gẹ́gẹ́ aláìlẹ́ṣẹ̀ iwájú rẹ̀. Bẹ́̀ ni èmi hu ìwà ìbàjẹ́ kan níwájú rẹ ìwọ ọba."

23 Inú ọba dùn gidigidi, ó pàṣẹ a Daniẹli jáde láti inú ihò. Nígbà a Daniẹli jáde nínú ihò, ojú ọgbẹ́ kan ara rẹ̀, nítorí ó gbẹ́kẹ̀Ọlọ́run rẹ̀.

24 Ọba pàṣẹ , a àwọn alátakò Daniẹli , a wọ́n inú ihò kìnnìún, pẹ̀ìyàwó àti àwọn ọmọ wọn. wọn ìsàlẹ̀ ihò, kìnnìún lágbára lórí i wọn, wọ́n fọ́ gbogbo egungun wọn.

25 Nígbà náà ni Dariusi ọba kọ̀gbogbo ènìyàn orílẹ̀-èdè, àti gbogbo jákèjádò ilẹ̀ náà:

"ìre yín máa pọ̀ i!

26 "Mo gbé àṣẹ kan jáde , gbogbo agbègbè ìjọba mi, gbogbo ènìyàn gbọdọ̀ bẹ̀, wọn ó bọ̀wọ̀ fún Ọlọ́run Daniẹli.

"Nítorí òun ni Ọlọ́run alààyè.

Ó títí ayé;

ìjọba rẹ̀ le è parun,

ìjọba rẹ̀ ìpẹ̀kun.

27 Ó ń yọ ni, ó ń gbani ;

ó ń ṣe iṣẹ́ àmì àti ìyanu

̀run àti ayé.

Òun gba Daniẹli

kúrò lọ́wọ́ agbára kìnnìún."

28 Daniẹli ṣe rere àkókò ìjọba Dariusi àti àkókò ìjọba Kirusi ti Persia.

Veja também