Pular para o conteúdo
Publicidade

João 6

6 Ó sọ èyí láti dán an ; nítorí òun fúnra rẹ̀ mọ ohun òun ó ṣe.

7 Filipi a lóhùn , "Àkàrà igba owó idẹ fún wọn, olúkúlùkù wọn tilẹ̀ í ju díẹ̀ jẹ."

8 6.8: Jh 1.40; 12.22. ̀kan nínú àwọn ọmọ-ẹ̀yìn rẹ̀, Anderu, arákùnrin Simoni Peteru fún un , 9 6.9: Jh 21.9-13."Ọmọdékùnrin kan ń bẹ níhìn-ín yìí, ó ìṣù àkàrà barle márùn-ún àti ẹja wẹ́wẹ́ méjì, ṣùgbọ́n kín ni ìwọ̀nyí jẹ́ láàrín ̀pọ̀ ènìyàn wọ̀nyí?"

10 Jesu , "àwọn ènìyàn náà jókòó!" Koríko púpọ̀ níbẹ̀. Bẹ́̀ ni àwọn ọkùnrin náà jókòó; ìwọ̀n ẹgbẹ̀rún márùn-ún (5,000) ènìyàn iye. 11 Jesu ìṣù àkàrà náà. Nígbà ó ti dúpẹ́, ó pín wọn fún àwọn ọmọ-ẹ̀yìn rẹ̀, àwọn ọmọ-ẹ̀yìn rẹ̀ pín wọn fún àwọn ó jókòó; bẹ́̀ gẹ́gẹ́ ni ẹja ìwọ̀n wọ́n ti ń fẹ́.

12 Nígbà wọ́n , ó fún àwọn ọmọ-ẹ̀yìn rẹ̀ , "àjẹkù ó jọ, ohunkóhun ṣe ṣòfò." 13 Bẹ́̀ ni wọ́n wọn jọ wọ́n fi àjẹkù ìṣù àkàrà barle márùn-ún náà kún agbọ̀n méjìlá, èyí àwọn ó jẹun jẹ .

Veja também