Pular para o conteúdo
Publicidade

Marcos 11

Igi ̀pọ̀tọ́ eṣo

20 11.20-25: Mt 21.20-22; Mt 17.20; Lk 17.6. òwúrọ̀ ọjọ́ kejì, wọ́n ti ń kọjá lọ, wọ́n igi ̀pọ̀tọ́ Jesu fi . Wọ́n i ó ti gbẹ tigbòǹgbò tigbòǹgbò. 21 Peteru rántí Jesu ti igi náà . Nígbà náà ni ó sọ fún Jesu , "Rabbi, ó! Igi ̀pọ̀tọ́ ìwọ fi ti gbẹ!"

22 Jesu dáhùn , "ìgbàgbọ́ nínú Ọlọ́run. 23 Lóòótọ́ ni fún un yín, ẹnikẹ́ni fún òkè Ṣídìí, gbé ara rẹ sọ sínú Òkun,ti ṣe iyèméjì nínú ọkàn rẹ̀ ṣùgbọ́n ó gbàgbọ́ ohun òun yóò ṣẹ, yóò bẹ́̀ fún un. 24 11.24: Jh 14.13-14; 16.23; Mt 7.7-11.Torí náà, mo fún yín ohunkóhun béèrè fún nínú àdúrà, ìgbàgbọ́ , ó tẹ̀ yín lọ́wọ́, yóò jẹ́ tiyín. 25 11.25: Mt 6.14-15; 18.35.Nígbà ń gbàdúrà, kọ́kọ́ dáríjì, ̀yin ohunkóhun ẹnikẹ́ni, baba yín ń bẹ ̀run à le dárí àwọn ̀ṣẹ̀ tiyín náà yín."11.25 Àwọn àkọsílẹ̀ àtijọ́ ìwé Marku kan se àfikún ọ̀rọ̀ yìí yín. 26 Ṣùgbọ́n bí ẹ̀yin bá kọ̀ láti dárí ẹ̀ṣẹ̀ àwọn ènìyàn jì wọ́n, baba yín kò ní í dárí ẹ̀ṣẹ̀ yín jì yín.

Veja também