Pular para o conteúdo
Publicidade

Marcos 9

17 Ọkùnrin kan láàrín ̀pọ̀ ènìyàn dáhùn , "Olùkọ́, èmi ni mo ọmọ yìí fún láti ó sàn. sọ̀rọ̀ rárá, nítorí ó ̀àìmọ́. 18 Àti , nígbàkígbà ó un, á gbé e ṣánlẹ̀, a máa itọ́ lẹ́nu, a máa lọ́ eyín rẹ̀. Òun pàápàá a le gbagidi. Mo bẹ àwọn ọmọ-ẹ̀yìn rẹ wọn ̀àìmọ́ náà jáde, ṣùgbọ́n wọ́n ṣe é."

19 Ó wọn lóhùn, ó , "̀yin ìran aláìgbàgbọ́ yìí, èmi yóò ti a yín gbé pẹ́ ? Èmi yóò ti sùúrù fún un yín pẹ́ ? ọmọ náà sọ́dọ̀ mi."

20 Wọ́n un sọ́dọ̀ rẹ̀: nígbà ó i, lójúkan náà ̀náà án tàntàn ó ṣubú lu ilẹ̀, ó ń fi ara yílẹ̀, ó ń yọ ìfófó lẹ́nu.

21 Jesu béèrè lọ́wọ́ baba ọmọ náà , "Ó ìgbà wo ọmọ rẹ̀ ti nínú irú ipò báyìí?"

Baba ọmọ náà dáhùn , "Láti kékeré ni." 22 Nígbàkígbà ni ó máa ń gbé e sínú iná àti sínú omi, láti pa á run, ṣùgbọ́n ìwọ ṣe ohunkóhun, ṣàánú fún wa, o ràn lọ́wọ́.

23 9.23: Mt 17.20; Lk 17.6; Mk 11.22-24. "Jesu fún un , ìwọ le gbàgbọ́: ohun gbogbo ni ó ṣe é ṣe fún ẹni ó gbàgbọ́.’ "

24 Lójúkan náà baba ọmọ náà kígbe ohùn rara, ó , "Olúwa, mo gbàgbọ́, ran àìgbàgbọ́ mi lọ́wọ́."

25 Nígbà Jesu i ̀pọ̀ ènìyàn ń péjọ sọ́dọ̀ wọn, ó ̀àìmọ́ náà , "Ìwọ ̀àìmọ́, adití àti odi, mo pàṣẹ fún , ó jáde kúrò lára ọmọ yìí, ó ṣe padà ibẹ̀ mọ́."

26 Òun kígbe ńlá, ó án tàntàn, ó jáde kúrò lára rẹ̀, ọmọ náà dàbí ẹni ó bẹ́̀ ̀pọ̀ ènìyàn , "è, ọmọ náà ti ." 27 Ṣùgbọ́n Jesu á lọ́wọ́, ó ràn án lọ́wọ́ láti dúró lórí ẹsẹ̀ rẹ̀. Ó dìde dúró.

Veja também