Pular para o conteúdo
Publicidade

Mateus 2

Ìbẹ̀àwọn amòye

1 2.1: Lk 2.4-7; 1.5. Lẹ́yìn ìgbà a Jesu Bẹtilẹhẹmu ti Judea, ni àkókò ọba Herodu, àwọn amòye ti ìlà-oòrùn Jerusalẹmu. 2 2.2: Jr 23.5; Sk 9.9; Mk 15.2; Jh 1.49; Nu 24.17.Wọ́n si béèrè , "Níbo ni ẹni náà a í ṣe ọba àwọn Júù ? Àwa ti ìràwọ̀ rẹ̀ ìlà-oòrùn, a láti foríbalẹ̀ fún un."

3 Nígbà ọba Herodu gbọ́ èyí, ìdààmú a àti gbogbo àwọn ara Jerusalẹmu pẹ̀rẹ̀. 4 Nígbà ó pe àwọn olórí àlùfáà àti àwọn olùkọ́ òfin jọ, ó bi wọ́n léèrè níbi ti a ó gbé Kristi? 5 2.5: Jh 7.42.Wọ́n , "Bẹtilẹhẹmu ti Judea, èyí ni ohun wòlíì ti kọ ìwé rẹ̀ ,

6 2.6: Mik 5.2. " Ṣùgbọ́n ìwọ Bẹtilẹhẹmu, ilẹ̀ Judea,

ìwọ kéré láàrín àwọn ọmọ-aládé Juda;

nítorí láti inú rẹ ni Baálẹ̀ kan yóò ti jáde,

ẹni ti yóò ṣe ìtọ́Israẹli, àwọn ènìyàn mi.’ "

7 Nígbà náà ni Herodu ọba pe àwọn amòye náà ìkọ̀kọ̀, ó wádìí ni ọwọ́ wọn, àkókò náà gan an wọ́n kọ́kọ́ ìràwọ̀. 8 Ó rán wọn lọ Bẹtilẹhẹmu, ó , "lọ ṣe ìwádìí fínní fínní ti ọmọ náà a . Lẹ́yìn i, padà sọ fún mi, èmi náà le lọ foríbalẹ̀ fún un."

9 Nígbà wọ́n gbọ́ ̀rọ̀ ọba, wọ́n ̀wọn pọ̀n, ó, ìràwọ̀ wọ́n ti láti ìhà ìlà-oòrùn , ó ṣáájú wọn, títí ó fi dúró lókè ibi ọmọ náà gbé . 10 Nígbà wọ́n ìràwọ̀ náà, ayọ̀ kún ọkàn wọn. 11 2.11: Mt 1.18; 12.46.wọ́n wọ inú ilé náà, wọn ọmọ ọwọ́ náà pẹ̀Maria ìyá rẹ̀, wọ́n wólẹ̀, wọ́n foríbalẹ̀ fún un. Nígbà náà ni wọ́n ìṣúra wọn, wọ́n ta Jesu lọ́rẹ: wúrà, tùràrí àti òjìá. 12 2.12: Mt 2.22; Ap 10.22; Hb 11.7.Nítorí Ọlọ́run ti kìlọ̀ fún wọn ojú àlá wọ́n ṣe padà tọ Herodu lọ mọ́, wọ́n gba ̀mìíràn lọ ìlú wọn.

Veja também