Pular para o conteúdo
Publicidade

Mateus 2

9 Nígbà wọ́n gbọ́ ̀rọ̀ ọba, wọ́n ̀wọn pọ̀n, ó, ìràwọ̀ wọ́n ti láti ìhà ìlà-oòrùn , ó ṣáájú wọn, títí ó fi dúró lókè ibi ọmọ náà gbé . 10 Nígbà wọ́n ìràwọ̀ náà, ayọ̀ kún ọkàn wọn. 11 2.11: Mt 1.18; 12.46.wọ́n wọ inú ilé náà, wọn ọmọ ọwọ́ náà pẹ̀Maria ìyá rẹ̀, wọ́n wólẹ̀, wọ́n foríbalẹ̀ fún un. Nígbà náà ni wọ́n ìṣúra wọn, wọ́n ta Jesu lọ́rẹ: wúrà, tùràrí àti òjìá. 12 2.12: Mt 2.22; Ap 10.22; Hb 11.7.Nítorí Ọlọ́run ti kìlọ̀ fún wọn ojú àlá wọ́n ṣe padà tọ Herodu lọ mọ́, wọ́n gba ̀mìíràn lọ ìlú wọn.

Veja também