Pular para o conteúdo
Publicidade

Matiu 22

Ìgbéyàwó nígbà àjíǹde

23 22.23-33: Mk 12.18-27; Lk 20.27-38. 22.23: Ap 4.1-2; 23.6-10. Ṣùgbọ́n ọjọ́ kan náà, àwọn Sadusi wọ́n sọ si àjíǹde lẹ́yìn ikú tọ Jesu láti bi í ìbéèrè, 24 22.24: De 25.5.wọ́n , "Olùkọ́, Mose fún wa , ọkùnrin kan àìlọ́mọ, arákùnrin rẹ̀ ṣú aya rẹ̀ lópó, ó ọmọ fún un. 25 ó jẹ́ bẹ́̀, láàrín wa níhìn-ín yìí, ìdílé kan ó arákùnrin méje. Èyí èkínní nínú wọn gbéyàwó, lẹ́yìn náà ó àìlọ́mọ. Nítorí náà ìyàwó rẹ̀ di ìyàwó arákùnrin kejì. 26 Bẹ́̀ gẹ́gẹ́ arákùnrin èkejì náà tún láìlọ́mọ. A fi ìyàwó rẹ̀ fún arákùnrin ó tún tẹ̀e. Bẹ́̀ ni títí òun fi di ìyàwó ẹni keje. 27 Níkẹyìn obìnrin náà pàápàá . 28 Nítorí ó ti ṣe ìyàwó àwọn arákùnrin méjèèje, ìyàwó ta ni yóò jẹ́ àjíǹde òkú?"

29 Ṣùgbọ́n Jesu wọn lóhùn , "Àìmọ̀kan yín ni ó fa irú ìbéèrè báyìí. Nítorí ̀yin mọ Ìwé Mímọ́ àti agbára Ọlọ́run. 30 Nítorí àjíǹde ìgbéyàwó, a fi í fún ni ìyàwó. Gbogbo ènìyàn yóò dàbí àwọn angẹli ̀run. 31 Ṣùgbọ́n nísinsin yìí, nípa ti àjíǹde òkú, tàbí ̀yin mọ̀ Ọlọ́run ń yín sọ̀rọ̀ nígbà ti ó : 32 Èmi ni Ọlọ́run Abrahamu, Ọlọ́run Isaaki, àti Ọlọ́run Jakọbu.Ọlọ́run í ṣe Ọlọ́run òkú, ṣùgbọ́n àwọn alààyè."

33 22.33: Mt 7.28. Nígbà ti àwọn ènìyàn gbọ́ èyí ẹnu wọ́n ̀kọ́ rẹ.

Veja também