Pular para o conteúdo
Publicidade

Jakọbu 3

7 Nítorí olúkúlùkù ̀ẹranko, àti ti ẹyẹ, àti ti ejò, àti ti ohun ó ń bẹ Òkun, ni à ń lójú, a ti lójú láti ọwọ́ ̀ènìyàn . 8 Ṣùgbọ́n ahọ́n ni ẹnikẹ́ni le lójú; ohun búburú aláìgbọ́ràn ni, ó kún fún oró ikú í pa ni.

Estes versículos te tocaram? Ore agora!

+581 estão orando agora.

Junte-se à corrente de oração.

Veja também