Pular para o conteúdo
Publicidade

1 Kọrinti 1

13 1.13: Mt 28.19; Ap 2.38. Ǹjẹ́ a ha pín Kristi ? Ṣé a kan Paulu mọ́ àgbélébùú fún un yín ? Ǹjẹ́ a tẹ̀ yín bọ omi orúkọ Paulu ? 14 1.14: Ap 18.8; Ro 16.23.Inú mi dún púpọ̀ èmi tẹ ẹnikẹ́ni nínú yín bọ omi yàtọ̀ Krisipu àti Gaiusi. 15 Nítorí náà ẹni ó sọ òun ṣe ìtẹ̀bọmi orúkọ èmi fúnra ara mi. 16 1.16: 1Kọ 16.15.(Bẹ́̀ ni, mo tún tẹ ìdílé Stefana bọ omi; lẹ́yìn èyí, èmí rántí mo tẹ ẹnikẹ́ni bọ omi mọ́ níbikíbi). 17 1.17: Jh 4.2; Ap 10.48; 1Kọ 2.1; 4.13.Nítorí Kristi rán mi láti máa ṣe ìtẹ̀bọmi, ṣùgbọ́n ó rán mi láti máa wàásù ìyìnrere: í ṣe nípa ọgbọ́n ènìyàn, a máa ṣe sọ àgbélébùú Kristi aláìlágbára.

Estes versículos te tocaram? Ore agora!

+581 estão orando agora.

Junte-se à corrente de oração.

Veja também