Pular para o conteúdo
Publicidade

1 Kọrinti 15

Àjíǹde Kristi

1 Ǹjẹ́ ará, èmi ń sọ ìyìnrere náà mọ̀ fún un yín, mo ti wàásù fún un yín, èyí ̀yin pẹ̀ti gbá, nínú èyí ̀yin dúró. 2 Nípasẹ̀ ìyìnrere yìí ni a fi ń gbà yín pẹ̀, ̀yin di ̀rọ̀ ti mo ti wàásù fún yín ṣinṣin. bẹ́̀ kọ̀, ̀yin kàn gbàgbọ́ lásán.

Estes versículos te tocaram? Ore agora!

+581 estão orando agora.

Junte-se à corrente de oração.

Veja também