Publicidade

Atos 2

17 2.17-21: Jl 2.28-32. "Ọlọ́run , ìkẹyìn ọjọ́,

Èmi yóò nínú ̀jáde sára ènìyàn gbogbo,

àwọn ọmọ yín ọkùnrin àti àwọn ọmọ yín obìnrin yóò máa sọtẹ́lẹ̀

àwọn ̀dọ́mọkùnrin yín yóò máa ríran,

àwọn arúgbó yín yóò máa àlá,

18 àti sára àwọn ọmọ ̀dọ̀ mi ọkùnrin àti sára àwọn ọmọ ̀dọ̀ mi obìnrin,

ni Èmi yóò nínú ̀mi jáde ni ọjọ́ wọ̀n-ọn-nì:

wọn yóò máa sọtẹ́lẹ̀.

19 Èmi yóò fi iṣẹ́ ìyanu hàn lójú ̀run,

àti àwọn àmì nísàlẹ̀ ilẹ̀;

̀jẹ̀ àti iná àti rírú èéfín;

20 A ó sọ oòrùn di òkùnkùn,

àti òṣùpá di ̀jẹ̀,

ọjọ́ ńlá àti ọjọ́ ológo Olúwa .

21 Yóò ṣe, ẹnikẹ́ni ó pe

orúkọ Olúwa ni a ó gbàlà.

Veja também

Bíblia Online Bíblia Online

Bíblia Online • Versão: 2026-07-04_15-35-42-