Pular para o conteúdo
Publicidade

Johanu 15

Àjàrà àti ̀ka rẹ̀

1 15.1: Isa 5.1-7; El 19.10; Mk 12.1-9; Mt 15.13; Ro 11.17. "Èmi ni àjàrà tòótọ́, Baba mi ni olùṣọ́gbà. 2 Gbogbo ̀ka nínú mi so èso, òun a kúrò, gbogbo ̀ka ó so èso, òun a wẹ̀ ́ mọ́, ó so èso i. 3 15.3: Jh 13.10.̀yin mọ́ nísinsin yìí nítorí ̀rọ̀ mo ti sọ fún yín. 4 15.4: Jh 6.56; 1Jh 2.6.máa gbé inú mi, èmi ó máa gbé inú yín. Gẹ́gẹ́ ̀ka ti so èso fún ara rẹ̀ ṣe ó ba ń gbé inú àjàrà, bẹ́̀ ni ̀yin, ṣe ń gbé inú mi.

5 "Èmi ni àjàrà, ̀yin ni ̀ka. Ẹni ó ń gbé inú mi, àti èmi nínú rẹ̀, òun ni yóò so èso lọ́pọ̀lọ́pọ̀, nítorí yíya ara yín kúrò lọ́dọ̀ mi, ṣe ohun kan. 6 ẹnìkan gbé inú mi, a gbé e sọnù gẹ́gẹ́ ̀ka, a gbẹ; wọn a wọn jọ, wọn a sọ wọ́n sínú iná, wọn a jóná. 7 15.7: Jh 14.13; 16.23; Mt 7.7; Jk 1.5.̀yin ń gbé inú mi, ̀rọ̀ mi gbé inú yín, ó béèrè ohunkóhun fẹ́, a ó ṣe é fún yín. 8 15.8: Mt 5.16.Nínú èyí a yìn Baba mi lógo , ̀yin ó máa so èso púpọ̀; ̀yin ó jẹ́ ọmọ-ẹ̀yìn mi.

Estes versículos te tocaram? Ore agora!

+581 estão orando agora.

Junte-se à corrente de oração.

Veja também