Pular para o conteúdo
Publicidade

Luku 7

Jesu òkú ọmọ opó kan dìde

11 7.11-17: Mk 5.21-24,35-43; Jh 11.1-44; 1Ọb 17.17-24; 2Ọb 4.32-37. ọjọ́ kejì, ó lọ ìlú kan a ń Naini, àwọn púpọ̀ nínú àwọn ọmọ-ẹ̀yìn rẹ̀ ń a lọ àti ̀pọ̀ ìjọ ènìyàn. 12 ó ti súnmọ́ ẹnu ibodè ìlú náà, kíyèsi i, wọ́n ń gbé òkú ọkùnrin kan jáde, ọmọ kan ṣoṣo náà ìyá rẹ̀ , ó jẹ́ opó: ̀pọ̀ ìjọ ènìyàn ìlú náà pẹ̀rẹ̀. 13 7.13: Lk 7.19; 10.1; 11.39; 12.42; 13.15; 17.5-6; 18.6; 19.8; 22.61; 24.3.Nígbà Olúwa i, àánú rẹ̀ ṣe é, ó fún un , "sọkún mọ́."

14 Ó , ó fi ọwọ́ tọ́ pósí náà: àwọn ń ú dúró jẹ́. Ó , "̀dọ́mọkùnrin, mo fún , dìde!" 15 Ẹni ó náà dìde jókòó, ó bẹ̀rẹ̀ i fọhùn. Ó á ìyá rẹ̀ lọ́wọ́.

16 7.16: Lk 7.39; 24.19; Mt 21.11; Jh 6.14. ̀ba gbogbo wọn: wọ́n yin Ọlọ́run lógo, , "Wòlíì ńlá dìde nínú wa," àti , "Ọlọ́run bẹ àwọn ènìyàn rẹ̀ !" 17 Òkìkí rẹ̀ kàn gbogbo Judea, àti gbogbo agbègbè ó i .

Veja também