Pular para o conteúdo
Publicidade

Luku 9

Jesu rán ọmọ-ẹ̀yìn méjìlá lọ wàásù

1 9.1-6: Mt 10.1,5,7-11,14; Mk 6.7-12; Lk 10.4-11. Ó pe àwọn ọmọ-ẹ̀yìn rẹ̀ méjìlá jọ, ó fún wọn agbára àti àṣẹ lórí àwọn ̀èṣù gbogbo, àti láti wo ààrùn sàn. 2 Ó rán wọn lọ wàásù ìjọba Ọlọ́run, àti láti àwọn ọlọkùnrùn láradá. 3 Ó fún wọn , "ṣe nǹkan lọ́wọ́ fún àjò yín, ̀, tàbí àpò tàbí àkàrà, tàbí owó, bẹ́̀ ni ̀yin ṣe ̀méjì. 4 ilékílé ̀yin wọ̀, níbẹ̀ ni ̀yin gbé, láti ibẹ̀ ni ̀yin ti jáde. 5 9.5: Ap 13.51.Iye àwọn si gbà yín, nígbà ̀yin jáde kúrò ìlú náà, gbọn eruku ẹsẹ̀ yín fún ̀wọn." 6 Wọ́n lọ, wọ́n ń la ìletò kọjá wọ́n ń wàásù ìyìnrere, wọ́n ń ènìyàn láradá níbi gbogbo.

Veja também