Pular para o conteúdo
Publicidade

Marcos 3

22 3.22-27: Mt 12.24-29; Lk 11.15-22. 3.22: Mt 9.34; 10.25. Àwọn olùkọ́ni òfin sọ̀kalẹ̀ láti Jerusalẹmu, wọ́n , "Ó ni Beelsebulu, olórí àwọn ̀èṣù, ni ó fi ń àwọn ̀èṣù jáde!"

23 Jesu wọ́n, ó fi òwe wọn sọ̀rọ̀: "Báwo ni Èṣù ṣe èṣù jáde? 24 ìjọba kan yapa ara rẹ̀, ìjọba náà yóò lulẹ̀. 25 Bákan náà, ilé kan yapa ara rẹ, ilé náà yóò le è dúró. 26 Èṣù dìde ara rẹ̀, ó yapa, òun yóò le è dúró ṣùgbọ́n òpin rẹ̀ yóò . 27 3.27: Isa 49.24-25.ẹni ó le wọ ilé ọkùnrin alágbára kan lọ, ó o ẹrù lọ, ṣe ó kọ́kọ́ de ọkùnrin alágbára náà okùn, nígbà náà ni yóò ẹrù ilé rẹ̀. 28 3.28-30: Mt 12.31-32; Lk 12.10.Lóòótọ́ mo fún yín, gbogbo ̀ṣẹ̀ ni a ó dáríjì àwọn ọmọ ènìyàn, àti gbogbo ̀rọ̀-òdì. 29 Ṣùgbọ́n ẹni ó sọ̀rọ̀-òdì ̀Mímọ́, yóò ìdáríjì títí ayé, ṣùgbọ́n ó nínú ewu ̀bi àìnípẹ̀kun."

30 Òun sọ eléyìí fún wọn, nítorí wọ́n sọ , "Nípa agbára ̀àìmọ́ ń ṣe àwọn iṣẹ́ ìyanu rẹ̀."

Veja também