Pular para o conteúdo
Publicidade

Matiu 22

37 22.37: De 6.5. Jesu dáhùn , " Fẹ́ Olúwa Ọlọ́run rẹ pẹ̀gbogbo ọkàn rẹ, gbogbo ̀rẹ àti gbogbo inú rẹ.38 Èyí ni òfin àkọ́kọ́ àti èyí ó tóbi jùlọ. 39 Èkejì ó tún dàbí rẹ̀ , Fẹ́ràn ọmọnìkejì rẹ gẹ́gẹ́ ara rẹ. 40 Lórí àwọn òfin méjèèjì yìí ni gbogbo òfin àti àwọn wòlíì rọ̀ mọ́."

Estes versículos te tocaram? Ore agora!

+581 estão orando agora.

Junte-se à corrente de oração.

Veja também