Pular para o conteúdo
Publicidade

Mateus 8

Ìwòsàn ọkùnrin ẹlẹ́mìí èṣù méjì

28 8.28-34: Mk 5.1-17; Lk 8.26-37. Nígbà ti ó apá kejì ilẹ̀ àwọn ara Gadara, àwọn ọkùnrin méjì ẹlẹ́mìí èṣù ti inú ibojì pàdé rẹ̀. Wọn rorò gidigidi bẹ́̀ ẹnikẹ́ni le kọjá ̀ibẹ̀. 29 8.29: On 11.12; 2Sa 16.10; Mk 1.24; Jh 2.4.Wọ́n kígbe lóhùn rara , "ṣe tàwa tìrẹ, Ìwọ Ọmọ Ọlọ́run? Ìwọ ha láti wa lóró ṣáájú ọjọ́ a yàn náà?"

30 Agbo ẹlẹ́dẹ̀ ńlá ń jẹ ń bẹ ̀jíjìn díẹ̀ wọn. 31 Àwọn ̀èṣù náà bẹ̀ Jesu , "ìwọ wa jáde, jẹ́ àwa ó lọ sínú agbo ẹlẹ́dẹ̀ yìí."

32 Ó fún wọn , "máa lọ!" Nígbà wọn jáde, wọn lọ sínú agbo ẹlẹ́dẹ̀ náà; ó, gbogbo agbo ẹlẹ́dẹ̀ náà rọ́ gììrì sọ̀kalẹ̀ bèbè odò bọ́ sínú Òkun, wọ́n ṣègbé nínú omi. 33 Àwọn ẹni ń ṣọ wọn , wọ́n ̀wọn pọ̀n lọ ìlú, wọ́n ròyìn ohun gbogbo, àti ohun a ṣe fún àwọn ẹlẹ́mìí èṣù. 34 Nígbà náà ni gbogbo ará ìlú náà jáde í pàdé Jesu. Nígbà wọ́n i, wọ́n bẹ̀ ́, ó lọ kúrò agbègbè wọn.

Veja também