Pular para o conteúdo
Publicidade

Rutu 1

11 Ṣùgbọ́n Naomi dáhùn , "padà sílé ̀yin ọmọ mi. Nítorí ni fi fẹ́ pẹ̀mi? Ṣé mo tún le àwọn ọmọkùnrin mìíràn ni, ó le ṣe ọkọ yin? 12 padà sílé, ̀yin ọmọ mi, nítorí èmi ti di arúgbó láti ọkọ mìíràn. èmí , èmí ìrètí, èmí tilẹ̀ ọkọ mìíràn alẹ́ yìí, èmí àwọn ọmọkùnrin mìíràn, 13 ̀yin ha le è dúró dìgbà wọ́n yóò fi dàgbà? ̀yin ó le è dúró wọ́n láì fẹ́ ọkọ mìíràn? Rárá, ̀yin ọmọbìnrin mi, nítorí inú mi bàjẹ́ gidigidi ju tiyín lọ, nítorí ọwọ́ Olúwa fi jáde mi!"

Estes versículos te tocaram? Ore agora!

+581 estão orando agora.

Junte-se à corrente de oração.

Veja também

Rute
Ver todos os capítulos de Rute