Pular para o conteúdo
Publicidade

1 Kọrinti 15

54 15.54: Isa 25.8.Ṣùgbọ́n nígbà ará ìdíbàjẹ́ yìí ti gbé àìdíbàjẹ́ wọ̀, ti ara kíkú yìí ti gbé àìkú wọ̀ bẹ́̀ tan, nígbà náà ni ̀rọ̀ ti a kọ yóò ṣẹ , "A gbé ikú ìṣẹ́gun."

55 "Ikú, oró rẹ ?

Ikú, ìṣẹ́gun rẹ́ ?"

56 Oró ikú ni ̀ṣẹ̀; àti agbára ̀ṣẹ̀ ni òfin. 57 Ṣùgbọ́n ọpẹ́ fún Ọlọ́run ẹni ó ìṣẹ́gun fún nípa Olúwa Jesu Kristi!

Estes versículos te tocaram? Ore agora!

+581 estão orando agora.

Junte-se à corrente de oração.

Veja também