Pular para o conteúdo
Publicidade

Oniwaasu 1

4 ìran kan ti ni ìran mìíràn ń kọjá lọ,

síbẹ̀ ayé dúró títí láé.

5 Oòrùn ń ràn, oòrùn ń wọ̀,

ó sáré padà ibi ó ti yọ.

6 Afẹ́fẹ́ ń fẹ́ lọ ìhà gúúsù,

Ó ń fẹ́ yípo ìhà àríwá,

a tún padà ̀rẹ̀.

7 Gbogbo odò ń sàn inú Òkun,

síbẹ̀síbẹ̀ Òkun kún.

Níbi àwọn odò ti ,

níbẹ̀ ni wọ́n tún padà .

Estes versículos te tocaram? Ore agora!

+581 estão orando agora.

Junte-se à corrente de oração.

Veja também