Pular para o conteúdo
Publicidade

Oniwaasu 11

6 Fún irúgbìn rẹ òwúrọ̀ kùtùkùtù,

ṣe jẹ́ ọwọ́ rẹ ṣọlẹ̀ àṣálẹ́,

nítorí ìwọ mọ èyí yóò ṣe rere

bóyá èyí tàbí ìyẹn

tàbí àwọn méjèèjì ni yóò ṣe dáradára bákan náà.

Estes versículos te tocaram? Ore agora!

+581 estão orando agora.

Junte-se à corrente de oração.

Veja também